Èdè Wa Ni: Ẹ Pàdé Ọmọọba Adéwálé Láoyè Tó Ń Ṣàkóso Ààfin Ìlù Ní Ìlú Ẹdẹ

A bá Ọmọọba Adewale Láoyè tí wọ́n jẹ́ olùṣàkóso Ààfin Ìlù ní Ìlú Ẹdẹ sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe ń ṣàfihàn àwọn ìlú ọlọ́kan-ò-jọ̀kan láti fi gbé àṣà àti ìṣe Yorùbá lárugẹ.

Read More: https://punchng.com/ede-wa-ni-e-pade-omooba-adewale-laoye-to-n-%e1%b9%a3akoso-aafin-ilu-ni-ilu-ede/

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *